from In the Garden of Joy
Ọgbà àjàrà ayọ̀ la wà yìí Dè mí kí n má lè rọ́nà yí Tilẹ̀kùn ọgbà àjàrà Kí nwọn ó máa gbẹ́kùlé wàrà. Kàn’lù ìfẹ́ sí mi Kí n jó dùndún ìfẹ́ mọ́jú Ràdò ìfẹ́ bò mí Má jẹ̀ẹ́ n ké’gbe òtútù. Bẹ́ẹ̀ bá wá’únjẹ wọ́gbà yìí wá Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ leè yó’kùn-un wa Báà wẹ̀ […]