A word to the wealthy
Ẹ métí bora kẹ́ gbóhun tí mo fẹ́ wí orin ewì ń gbé mi nínú Ibi mo sọ̀rọ̀ dé ni ngó fàbọ̀ sí Orin ọgbọ́n ṣẹ́kù nínú mi Orin olówó lorin tó yó sí mi lẹnu Kò sí gbàrọgùdù mọ́, orin olówó ló kù nílẹ̀ Mo ní b’ọ́lọ́lá ayé ti lọ́lá tó Ọlọ́lá ò le […]